Abàmì ẹlẹ́dẹ̀ tí dífá fún Super Eagles nípa Russia 2018 Olayemi Oniroyin 6/15/2018 05:51:00 pm Add Comment Edit Ẹlẹ́dẹ̀ abàmì tó sọ àsọtẹ́lẹ̀ nípa wí pé, Donald J. Trump ìlú Amẹrika ni yóò jaye olubori gẹ́gẹ́ bí Ààrẹ ilẹ̀ Amẹ́ríkà tí kéde wí pé ikọ́ a... Read More
Russia 2018: Pele àti Maradona tí wọlé Olayemi Oniroyin 6/12/2018 07:53:00 am Add Comment Edit Ààrẹ ìlú Russia 🇷🇺, Putin, fún ra rẹ lo kí Pele kaabọ si orile-ede Russia fún igbaradi ìfẹ́ agbaye tí yóò wayé ni or... Read More
"Mikel Obi kìí rán àwọn ènìyàn rẹ lọ́wọ́"- Ẹbi Mikel kan tí sọ̀rọ̀ Olayemi Oniroyin 5/10/2018 06:33:00 pm Add Comment Edit Ọmọkùnrin kan lórí ayélujára ti gbìyànjú láti fi aṣọ Mikel Obi yidọti. Ọmọkùnrin náà ṣe àlàyé ara rẹ gẹ́gẹ́ bí ọmọ àbúrò bàbà Mikel. Ó ni ar... Read More
Arsene Wenger tí kéde ifehinti rẹ Olayemi Oniroyin 4/23/2018 02:22:00 pm Add Comment Edit Ẹ kíyèsí, àlàyé to bá ti ní nọ́mbà kìí rújú. Nǹkan bí ọdún méjìlélógún lo fi tukọ̀ ẹgbẹ́ agbaboolu Arsenal gẹ́gẹ́ bí akonimọọgba. Igba mẹta ... Read More
Ọwọ Anthony Joshua, ọmọ ológo, ni àgbà wá báyìí Olayemi Oniroyin 4/01/2018 01:40:00 pm Add Comment Edit Ẹ wí fún ẹni tí kò bá mọ kí wọn lọ mọ wí pé, ọwọ́ Anthony Oluwafemi Olaseni Joshua nìkan ni ẹ ti lè rí àmì ẹyẹ agbaye WBA, IBF, WBO ati IBO.... Read More
Anthony Joshua Oluwafemi to bẹru Olayemi Oniroyin 4/01/2018 12:46:00 am Add Comment Edit Anthony Olaseni Oluwafemi Joshua ṣe àfihàn àwọn àmì ẹyẹ rẹ lẹ́yìn to fo gbogbo ẹnu Joseph Parker nínú ìjà to wáyé lọjọ Satide, 31/03 /2018 ... Read More
Jatijati ni Anthony Joshua na Joseph Parker ni àlè ana Olayemi Oniroyin 4/01/2018 12:23:00 am Add Comment Edit Ninu idije ese kíkan tó wáyé ní ilẹ Biritiko lọjọ Satide to kẹyin oṣù kẹta, 31/03/2018, àná fò lójú ni Anthony Joshua na Joseph Parker Read More
A má tí orí Morocco bonu omi gbígbóná ni to bá di Sunday - Super Eagles Olayemi Oniroyin 2/02/2018 08:57:00 am Add Comment Edit Asekagba idije Chan 2018 eléyìí to ń wáyé ní orileede Morocco ni yóò wá sopin lọjọ Sande tí ń bo yii. Asekagba náà yóò sì wáyé láàárín Sup... Read More
C. Ronaldo kò àwọn ẹbí rẹ wọnú omi Olayemi Oniroyin 2/01/2018 11:03:00 am Add Comment Edit Omo to bá ń sise dééde, ó yẹ kó ni asiko isimi. Kosi sì ohun tó dùn bí kí ènìyàn ló isimi rẹ pẹlu awọn ẹbi rẹ. C Ronaldo lọ ṣe àfihàn òun à... Read More
Awon foto eto igbeyawo Lionel Messi ati aya re ni Argentina Olayemi Oniroyin 7/01/2017 08:58:00 am Add Comment Edit Gbogbo orileede Argentina lo mi titi nigba ti awon irawo agbaboolu kaakiri agbaye si baalu wole kaakiri origun meererin agbaye nibi ti ... Read More